Showing posts with label Born Divine. Show all posts
Showing posts with label Born Divine. Show all posts

Friday, March 20, 2015

Mayowa Adeyemo praises Eledumare (Creator)


Odíderé ayékòótá máa wolè máràba
Odéderé ayébòútó máa wolè máràba
oò ri' báyé nwá doríto dò tó dobúépo
ọmọ ò gbọ́ tí baba mo, baba ò gbó dimọ má, aya ò gbọ́ lọkọ mo
gbogbo rè wá polúkúrámusu nílé ayé o
Elédùmarè e, Olódù só màre
Òbá wá bá wa túnlé ayé se
Káyé ó máse dàrú má
Káyé ó rójú, káyé ó ráàyè
Kóòdè ó gba gbogbo wa nílé ayé
Torílé ayé yìí kansoso la wá
Àjò sì nilé ayé
Gbogbo wa la ó padà relí bóbá dọjọ́ kaa
Elédùmarè o o o
Ìwọ mà lọ̀mọ̀ràn tí moyún ìgbín nínú ìkọrọhua
Ìwọ mà leni tó tọgbọ́n mọgbá orí
Ìwọ mà leni tó dá gbogbo wa rílé ayé
Tí wọ́n ti ń pelé ayé nílé dúníyàn o
Elédùmarè ọba toto bọ bí orí
Bíyá tín bì ó díè kórí ire ó lè wá
Bo lè dámí l'óhùn gbogbo ohun tí mo bá
bèrè lọ́wọ́ ò ré lújúọ tòní o
Oba atérere káré ayé, Ọba kòṣeuntì
Òbàmùbárá matéré bamba
Elédùmarè
Ènìyàn wèròwèsò tí ò sée lowó wàdùwàdù mú
Enítóbá tasè àgèsè pérén
Kódà á sanwó láyé, á wá lo rèé sekà lórun ni
Elédùmarè o o o
Ọba ńlá, tí ò seé gbíjá, ọba tí ò seé gbìjà
Torí mọ súmóba níwọ̀n egbèje
Mo jìnnà sóba níwọ̀n egbejà
mi ò mà róba fín torá róba fiń loba ń pa
Ọba tótó bí aró, ọba rèrè bí osùn
Eléní àtèká gbogbo mekùn oòyè
Òpó àndù oyè
Ọba tí wọ́n kìí bá du oyè láíláí
L'elédùmarè ọba tèmi
Ọ̀bá dákun o gbébè mi
Ọ̀bá dákun o gbébè mi
Káyé ó ńjú fún wa
Káyé ó ńjú fún wa
Kílè yí ó sàn wá
Kílè yíí ó san wá
Kámáse rógun àdáyà
Kámáse rógun àgbédá
Kámáse rógun àkóbá
Lólá Elédùmarè jóo bá jé gbó àdúrà wa
Mose tótó, mo se sákì olú
Gbogbo èyí náà, ko ba lè gbóhùn èbè mi ni
Ọ̀bá dákun wá gbọ́ o o o

Mayowa Adeyemo praises Ogun (God of Iron)


Ògún onírè ọkọ ò mi
Irúnmolè tí ń rù mìnìmìnì
Òlómi nílé fèjè wè
Òlása nílé fìmọ̀bímọ̀ bora
Ògún aládàá méjì
Ó fìkán sánko, ó fìkán yènà
Ojó Ògún ń fìkòlé òrun bò wá s'ílé ayé
Asa iná ló mú bora
èwù èjè ló wọ̀ sọ́rùn o
Ògún onílé owó ọlọ́nà ọla
Ògún onílé kángun kàngun òde òrun
Méje l'Ògún mi
Ògún alárá nií gbajá
Ògún onírè a gbàgbò
Ògún ìkọlà a gbà 'gbín
Ògún elémoná nií gbèsun asu
Ògún akirun á gbà wo àgbò
Ògún gbénàgbénà eran ahun níí je
Ògún mákinde ti d'Ògún léhìn odi
Bí ò bá gba tápà á gbàbókí á gba húnkùnhúnkùn
á gba tèmbèrí o jàre
mo ní e má bógúnrún fìjà seré
Ògún òlódodo l'Ògún tèmi
Ọmọ Orórínà, ọmọ Tàbúfú
Morú nítorípé l'ójó Ògún kó délé ayé,
Emu ló kó bèrè o ḿgbà tó délè ìrè o
Ògún onílé owó, Olónà olà
Ògún ónile, kángunkàgun òde òrun
Mo ní e má aàbógùn fìjà sére o o
Ara Ògún kan gó gó gó

Everyday racism: What Should We Do? by Akala


These racial assumptions lead to 'everyday' racism - daily encounters and micro-agressions. It's time to recognize the relationship between top-down propaganda and the bias that we all carry.

Friday, March 6, 2015

Book Review: Ifa In Yoruba Thought System by Omotade Adegbindin

    Previous scholars of Ifá have conveyed an impression that Ifá is a characteristic social institution with only religious, ethnographical and sociological significance. In fact, Ifá has been greatly misconceived as a mere religious and mythic discourse, devoid of any meaningful philosophical import. There is also the misconception that Ifá is now largely anachronistic. In Ifá in Yorùbá Thought System, the author shows that an adequate understanding of a text requires a transition from the manifest to the latent meaning and, therefore, analyses the Ifá literary corpus with a view to identifying the aspects of Ifá that are of philosophic relevance. He shows that fundamental philosophical issues, including nature of reality, knowledge, human conduct are embedded in Ifá. With reflective interpretation of an appreciable number of Ifá verses, the author also examines the utilitarian functions of Ifá, offers good insight into important political ideas and values that are relevant to much of the political challenges in contemporary society and how scientific and technological development can be enhanced within the context of the Yorùbá oral tradition. In all, this book shows that the Ifá literary corpus, as a complete philosophy, has the prospect of providing a firm ground for the resolution of some of the pressing problems confronting contemporary societies.

     This book is part of the African World Series, edited by Toyin Falola, Jacob and Frances Sanger Mossiker Chair in the Humanities, University of Texas at Austin.

Order Now


Ifa In Yoruba Thought System is a great read that extends our perspective on Ifa and how Ifa as a cultural spirituality relates to “philosophy”. In this book, Omotade Adegbindin covers ontology, epistemology, and ethics in the Ifa Corpus. He also explores both literacy and the development crisis in Africa from an Ifa perspective, which he supports with Odu Ifa. I believe this book is a great contribution to the Ifa World Community and hope that there are more works like this to come.

*** If you are interested in Ifa In Yoruba Thought System you may also want to download: The Problems Of Gerontocracy In Africa: The Yoruba Perspective As Illustrated In Ifa Corpus by Omotade Adegbindin

Mark "Born Divine" Anthony (Ifasalewa)
egbe Ogun si wa | ATL